Surprise Castle
Ọlọrun ni Olùpamọ́ Rẹ

Ọlọrun ni Olùpamọ́ Rẹ - Paperback

$9.99
Quantity
01

Pay over time for orders over $35.00 with

Offers & Perks

Earn 9 points with this purchase

Added to your rewards balance after checkout.

100 points welcome bonus

Create an account and start with extra points.

Join now
Availability:In StockContributor:Philip O. AkinyemiSeries:Ọlọrun Ni Olùpamọ́ RẹTheme:Religious Orientation/ChristianAudience:Baby-PreschoolPublish date:9/5/2019Pages:32
Languages:YorubaPublisher:Fmp365ISBN-13:9780997923865ISBN-10:0997923865UPC:9780997923865Book Category:Juvenile NonfictionBook Subcategory:Religious, Biography & Autobiography, ReligionBook Topic:Christian, Religious, ChristianitySize:8.50 x 8.50 x 0.08 inchesWeight:0.1Product ID:SCRKZC3VA0

Awọn itan Bibeli ti inu iwe yi yio jẹ iranwọ fun awọn ọmọde lati mọ pe (ranti pe) ohunkohun yo wu ti ńsẹlẹ ninu aiye wọn tabi ni ayika wọn, Ọlọrun ntọju, bẹni O si ńsọ wọn lọsan ati loru. Ko dabi awọn obi wa, Ọlọrun ki i sun tabi ko sarẹ. Ọlọrun si mọ ọjọ waju. O jẹ olododo ati Ẹniti ńpa adehun Rẹ mọ.

Languages:YorubaPublisher:Fmp365ISBN-13:9780997923865ISBN-10:0997923865UPC:9780997923865Book Category:Juvenile NonfictionBook Subcategory:Religious, Biography & Autobiography, ReligionBook Topic:Christian, Religious, ChristianitySize:8.50 x 8.50 x 0.08 inchesWeight:0.1Product ID:SCRKZC3VA0
Akinyemi, Philip O.: - "Dr. Philip O. Akinyẹmi jẹ ọmọ ẹgbẹ awọn ti ńkọ iwe ati aworan fun awọn ọmọde ti ańpe ni (Society of Children's Book Writers and Illustrators - SCBWI). O ńgbe ni ipinlẹ Georgia ti America. Ninu awọn iwe ti o kọ ni "The Holy Spirit and Knowing God." Ẹdun ọkan rẹ ni lati mọ Ọlọrun timọtimọ ati lati jẹ ki awọn enia mọ ọ daradara."
Publisher: Fmp365

Edition

L Run Ni Olupam Edition

Free shipping on orders over $75. Standard shipping takes 3-7 business days. Returns accepted within 30 days of purchase.